Ìwé kíkọ

Ìwé kíkọ
Láì sí ọ’kọ’
Àti adá
Kò ì pé ó
Kò ì pé ò
Ìṣẹ’ àgbè
Ní ṣẹ ilẹ’ wá
Ẹnì kò ṣíṣe
A máa jalè
Ìwé kíkọ
Láì sí ọ’kọ’
Àti adá
Kò ì pé ó
Kò ì pé ò
Ìṣẹ’ àgbè
Ní ṣẹ ilẹ’ wá
Ẹnì kò ṣíṣe
A máa jalè

Ìsapá
Láì sí iyán
Àti ẹ’gusi
Kò ì pe ó
Kò ì pé ò
Iyán at’ ẹbá
Lounjẹ’ ilẹ’ wa
Ẹni kò jẹ’ ‘yán
A jẹ’ bà tó tútù
Ìsapá
Láì sí iyán
Àti ẹ’gusi
Kò ì pe ó
Kò ì pé ò
Iyán at’ ẹbá
Lounjẹ’ ilẹ’ wa
Ẹni kò jẹ’ ‘yán
A jẹ’ bà tó tútù

Translation: Education without knowledge about agriculture is incomplete. Farming is our culture. Anyone who doesn’t work may end up stealing.

Category: